Ìṣẹ̀lẹ̀ ìbànújẹ́ ti jíjí àwọn ọmọ ilé-ìwé àti àwọn olùkọ́ wọn gbé ní Ìpínlẹ̀ Ọyọ́ ti dá ọ̀pọ̀ ènìyàn láàmú, nígbà tí awakọ̀ kan náà pa ọmọ mẹ́ta ní Ìpínlẹ̀ Rivers nínú ìjàmbá ọkọ̀. A ó bẹ̀rẹ̀ ìtẹ̀jáde Ìwòye ọ̀sẹ̀ yìí pẹ̀lú àwọn ìròyìn ìbànújẹ́ wọ̀nyí. Síbẹ̀, bí Arsenal ṣe gba akọ́lé Premier League lẹ́yìn ọdún méjìlélógún [22] tí wọ́n ti ń dúró mú ìdùnnú bá àwọn olólùfẹ́ ẹgbẹ́ náà káàkiri ayé. Ẹ gbọ́ ìṣẹ̀lẹ̀ wọ̀nyí ní ìsàlẹ̀!
Disclaimer
Comments expressed here do not reflect the opinions of Vanguard newspapers or any employee thereof.