Top Podcasts

Akẹ́kọ̀ọ́ ilé-ẹ̀kọ́ gíga, Olamide, kú lẹ́yìn tí wọ́n fipá mú un kọ ìdánwò nígbà tó ń ṣàìsàn; Akẹ́kọ̀ọ́ pàdánù ẹ̀mí ní Yábà lẹ́yìn tó kẹ́nu ìfẹ́ sí ọ̀rẹ́bìnrin aṣáájú ẹgbẹ́ òkùnkùn

Akẹ́kọ̀ọ́ ilé-ẹ̀kọ́ gíga, Olamide, kú lẹ́yìn tí wọ́n fipá mú un kọ ìdánwò nígbà tó ń ṣàìsàn; Akẹ́kọ̀ọ́ pàdánù ẹ̀mí ní Yábà lẹ́yìn tó kẹ́nu ìfẹ́ sí ọ̀rẹ́bìnrin aṣáájú ẹgbẹ́ òkùnkùn

Lórí ètò Ìwòyé lónìí: Akẹ́kọ̀ọ́ ilé-ẹ̀kọ́ gíga, Olamide, kú lẹ́yìn tí wọ́n fipá mú un kọ ìdánwò nígbà tó ń ṣàìsàn. Deborah, ọmọ ọdún méjìlélógún, kú nígbà tó ń ṣe ayẹyẹ ọjọ́ ìbí rẹ̀ pẹ̀lú ọ̀rẹ́kùnrin rẹ̀ ní ilé-ìtura. Akẹ́kọ̀ọ́ pàdánù ẹ̀mí ní Yábà lẹ́yìn tó kẹ́nu ìfẹ́ sí ọ̀rẹ́bìnrin aṣáájú ẹgbẹ́ òkùnkùn
Visible Articles 5 10 15
Ìwòye: Àwọn aládùgbò dawo lu ọkùnrin kan pa ní Ìpínlẹ̀ Ògùn; Àwọn ọlọ́pàá rí agbárí mẹ́jìdínlọ́gbọ̀n nínú igbó ní Ìpínlẹ̀ Abíà

Ìwòye: Àwọn aládùgbò dawo lu ọkùnrin kan pa ní Ìpínlẹ̀ Ògùn; Àwọn ọlọ́pàá rí agbárí mẹ́jìdínlọ́gbọ̀n nínú igbó ní Ìpínlẹ̀ Abíà

Ní ọ̀sẹ̀ yìí lórí ètò Ìwòyé: Àwọn aládùgbò dawo lu ọkùnrin kan pa ní Ìpínlẹ̀ Ògùn; Àwọn ọlọ́pàá rí agbárí mẹ́jìdínlọ́gbọ̀n nínú igbó kan ní Ìpínlẹ̀ Abíà, Ọ̀pọ̀ ènìyàn pàdánù owó ní ìlú Ọ̀ṣọ́gbò, lẹ́yìn tí wọ́n bá àwọn ẹlẹ́tàn kan ṣe.

Ìwòye: Ọ̀dọ́ akẹ́kọ̀ọ́ kan pa ara rẹ̀ lẹ́yìn tó padà láti àgọ́ ọlọ́pàá ní Ìpínlẹ̀ Ọ̀yọ́. Omọkùnrin kan pa ìyá rẹ̀ ní Ìpínlẹ̀ Abíà

Ìwòye: Ọ̀dọ́ akẹ́kọ̀ọ́ kan pa ara rẹ̀ lẹ́yìn tó padà láti àgọ́ ọlọ́pàá ní Ìpínlẹ̀ Ọ̀yọ́. Omọkùnrin kan pa ìyá rẹ̀ ní Ìpínlẹ̀ Abíà

Akẹ́kọ̀ọ́ kan pa ara rẹ̀ lẹ́yìn tó padà láti àgọ́ ọlọ́pàá ní Ìpínlẹ̀ Ọ̀yọ́. Omọkùnrin kan pa ìyá rẹ̀ ní Ìpínlẹ̀ Abíà; Awọn ọlọ́pàá ti mú ọkùnrin kan tí wọ́n fẹ̀sùn kàn pé ó lu ọmọdé kékeré kan ní Ìkọ̀rọ̀dú.

One Vote: The Voter’s Campaign Checklist

One Vote: The Voter’s Campaign Checklist

Campaigns matter because they are supposed to give voters an opportunity to hear what candidates intend to do, question them, compare their proposals with their records, and decide what matters to them. The danger is that campaigns can also become dominated by slogans, personality politics, endorsements, social-media battles and promises that are difficult to verify. […]

Agbo olóró pa ọ̀pọ̀lọpọ̀ ènìyàn ní Ìpínlẹ̀ Ondó; Àwọn ọlọ́pàá ti mú tọkọtaya lẹ́yìn tí wọ́n fi ẹ̀sùn kàn wọ́n pé wọ́n ti ọmọbìnrin Amarachi mọ́ ilé ìgbọ̀nsẹ̀ ní Ìpínlẹ̀ Rivers

Agbo olóró pa ọ̀pọ̀lọpọ̀ ènìyàn ní Ìpínlẹ̀ Ondó; Àwọn ọlọ́pàá ti mú tọkọtaya lẹ́yìn tí wọ́n fi ẹ̀sùn kàn wọ́n pé wọ́n ti ọmọbìnrin Amarachi mọ́ ilé ìgbọ̀nsẹ̀ ní Ìpínlẹ̀ Rivers

Ní ọ̀sẹ̀ yìí lórí ètò Ìwòyé:  Agbo olóró pa ọ̀pọ̀lọpọ̀ ènìyàn ní Ìpínlẹ̀ Ondó; Ìkọlù sí lèmọ́mù kan mú kí ìjọba ti mọ́ṣáláṣí kan ní Ìpínlẹ̀ Sókótó; Àwọn ọlọ́pàá ti mú tọkọtaya lẹ́yìn tí wọ́n fi ẹ̀sùn kàn wọ́n pé wọ́n ti ọmọbìnrin Amarachi mọ́ ilé ìgbọ̀nsẹ̀ ní Ìpínlẹ̀ Rivers.