Top Podcasts

Ìwòye: Emir Kàtsínà kìlọ̀ fún àwọn olóṣèlú pé kí wọn mú ìlérí tí wọn ṣe lásìkò ìpòlongo ìbò ṣẹ; Ààrẹ Bọ́lá Tinúbú fi ẹ̀sùn kan àwọn alátakò pé àwọn ló fa ìṣẹ́ àti òṣì orílẹ̀-èdè Nàìjíríà jẹ́

Emir Kàtsínà, Àlhájì Kábíù Úsmán tí kìlọ̀ fún àwọn olóṣèlú pé kí wọn rí dájú láti mú ìlérí tí wọn ṣe lásìkò ìpòlongo ìbò fún àwọn aráàlú ṣẹ; Ààrẹ Bọ́lá Tinúbú fi ẹ̀sùn kan àwọn alátakò pé àwọn ló fa ìṣẹ́ àti òṣì rílẹ̀-èdè Nàìjíríà jẹ́.
Visible Articles 5 10 15

Favour pa ara rẹ̀ nítorí pé arákùnrin Ifáyín Ọ̀gbọ́nnà fi ipá bá a lòpọ̀ ní Ìpínlẹ̀ Delta; Musbau pa ìyàwó rẹ̀ nítorí oúnjẹ ní Ìpínlẹ̀ Nasarawa

Ní orí ètò Ìwòyé ọ̀sẹ̀ yìí: Arábìnrin Favour pa ara rẹ̀ nítorí pé arákùnrin Ifáyín Ọ̀gbọ́nnà fi ipá bá a lòpọ̀ ní Ìpínlẹ̀ Delta; Olùkọ́ ilé-ìwé gíga dá akẹ́kọ̀ọ́ kan dúró fún ọdún méjì nítorí “fẹ́ mi, mo fẹ́ ẹ”; arákùnrin Musbau pa ìyàwó rẹ̀ nítorí oúnjẹ ní Ìpínlẹ̀ Nasarawa.

Exit mobile version