Top Podcasts

One Vote: The Voter’s Campaign Checklist

Campaigns matter because they are supposed to give voters an opportunity to hear what candidates intend to do, question them, compare their proposals with their records, and decide what matters to them. The danger is that campaigns can also become dominated by slogans, personality politics, endorsements, social-media battles and promises that are difficult to verify. […]
Visible Articles 5 10 15

Ìwòye: Abilékọ Oluchi jí ara rẹ̀ gbé fún àádọ́ta mílíọ̀nù naira; àwọn òṣèré ṣe ìkẹ́dùn leyin iku olóògbé Alex Ekubo

Abilékọ kan tí orúkọ rẹ̀ ń jẹ́ Oluchi jí ara rẹ̀ gbé fún àádọ́ta mílíọ̀nù náírà; ọ̀dọ́mọkùnrin kan ké gbàjaré pé àwọn agbésùnmọ̀mí fẹ́ gba ọgọ́rùn mílíọ̀nù náírà lọ́wọ́ rẹ̀ leyin tó gba owó lọ́wọ́ won; àwọn òṣèré Nollywood ṣe ìkẹ́dùn ìkẹ́hìn ati orin ìdágbérefún olóògbé Alex Ekubo

Ìwòye: Àwon olùkọ́ ṣèfẹ̀hónúhàn lórí àwọn akẹ́kọ̀ọ́ wọ́n jígbé ní Ọ̀yọ́; Ilé ẹjọ́ dá ẹ̀bi ikú fún àwọn tó kọlù ṣọ́ọ̀ṣì Òwò

Àjọ NUT bẹ̀rẹ̀ Ìfẹ̀hónúhàn káàkiri orílẹ̀-èdè lórí jíjí àwọn ènìyàn gbé ní Ọ̀yọ́; Ilé ẹjọ́ dá mẹ́rin lẹ́bi ikú nítorí ìkọlù Ọ̀wọ̀; wọ́n jí àbúrò obìnrin òṣìṣé ìjọba àpapọ̀ tẹ́lẹ̀ rí àti àwọn ọmọkùnrin ìbejì rẹ̀ gbé.

Exit mobile version