Top Podcasts

Iwoye: Àwọn ọlọ́pàá mú ènìyàn mẹ́ta ní ìlú Jos nítorí ikú Ibrahim ti won fi esun ole kan…

Ní ọ̀sẹ̀ yìí lórí Ìwòyé: Àwọn ọlọ́pàá mú ènìyàn mẹ́ta ní ìlú Jos nítorí ikú Ibrahim to win fi esun ole kan; wọ́n tún mú awakọ̀ kan ní Ìjẹ̀bú-Òde, nítorí ìjàmbá tí wọ́n ní ó mọ̀ọ́mọ̀ fà, tó sì ṣokùnfà ikú arìnrìn-àjò kan; wọ́n sì mú onigbajamo kan ní Ìpínlẹ̀ Abíà lórí ẹ̀sùn lílo irun […]
Visible Articles 5 10 15

Wọ́n jí àwọn ọmọ ilé-ìwé àti àwọn olùkọ́ wọn gbé ní Ìpínlẹ̀ Ọyọ́; awakọ̀ kan pa ọmọ mẹ́ta ní Rivers, Arsenal gba ife liigi

Ìṣẹ̀lẹ̀ ìbànújẹ́ ti jíjí àwọn ọmọ ilé-ìwé àti àwọn olùkọ́ wọn gbé ní Ìpínlẹ̀ Ọyọ́ ti dá ọ̀pọ̀ ènìyàn láàmú, nígbà tí awakọ̀ kan náà pa ọmọ mẹ́ta ní Ìpínlẹ̀ Rivers nínú ìjàmbá ọkọ̀. A ó bẹ̀rẹ̀ ìtẹ̀jáde Ìwòye ọ̀sẹ̀ yìí pẹ̀lú àwọn ìròyìn ìbànújẹ́ wọ̀nyí. Síbẹ̀, bí Arsenal ṣe gba akọ́lé Premier League lẹ́yìn […]

ONE VOTE: Consensus Dilemma

This week’s ONE VOTE takes a look at the consensus dilemma across political parties as they select candidates for the 2027 elections.

How church shaped, limited our music journey — Afrobeat pioneer, Twin-X

Afrobeats duo Twin-X have returned to the spotlight, reflecting on fame, faith and the lasting impact of their timeless hit Mother Mi during an appearance on the Nigerian Meter Podcast. The identical twin brothers, Taiwo and Keni Akintoye, said the song was inspired by personal experiences and went on to become a cultural anthem of the early 2000s.

Exit mobile version