Top Podcasts

Ìwòyé: Iná pa àwọn mẹ́rin nínú ìdílé kan ní Yobe lẹ́yìn tí ọmọdé kan dá iná sí ilé náà; NDLEA mú obìnrin àgbà kan tó jẹ́ ìyá-àgbà, ẹni ọdún 83, nígbà tí wọ́n ṣe ìwádìí nípa oògùn olóró ní Abia

Ní ọ̀sẹ̀ yìí lórí ètò Ìwòyé: Ní Yobe, èèyàn mẹ́rin nínú ẹbí kan kú lẹ́yìn tí ọmọ ọdún mẹ́sàn-án dáná sun’lé. Àjọ NDLEA mú ìyá àgbà ẹni ọdún mẹ́tàlélọ́gọ́rin lórí ẹ̀sùn gbígbé oògùn olóró ní Abia. Awọn ọlọ́pàá tì mú ọkùnrin kan ní Ìpínlẹ̀ Imo lórí ẹ̀sùn jíjínigbé àti pípa olólùfẹ́ rẹ̀
Visible Articles 5 10 15

Olùkọ́ Maryam Usman sòfò ẹ̀mí lẹ́yìn tí bàbá akẹ́kọ̀ọ́ rẹ̀ lù ú ní àlùbami; ìkún omi ojijì dá omiyálẹ̀ sí ilé ní Ìlú Èkó

Ní ọ̀sẹ̀ yìí lórí ètò Ìwòyé: Olùkọ́ Maryam Usman sòfò ẹ̀mí lẹ́yìn tí bàbá akẹ́kọ̀ọ́ rẹ̀ lù ú ní àlùbami; àwọn ẹ̀ṣọ́ ààbò gba àwọn ọmọ méjì là lọ́wọ́ àwọn ajínigbé ní Ìpínlẹ̀ Ọ̀yọ́; ìkún omi ojijì dá omiyálẹ̀ sí ilé ní Ìlú Èkó…

Exit mobile version