ORIKI Ooni Oba Adeyeye Ogunwusi Ojaja Keji
ORIKI Kabiyesi Ooni Oba Adeyeye Ogunwusi Ojaja Keji Omo Ojaja fidi ote jale Omo Ayi kiti Ogun Omo etiri Ogun Kare o Leyoo aje okun Ooni Ajere aboju jojo Oke leyin Moore O taye so bi igba Omo Laade Omo Ibi ro Omo ajongbodo Omo osun meru ti kun Omo ibi ola ti n wa […]